Logo Lanfrica
  • Accueil
  • Atlas
  • Analyses
  • Documentation
  • Sign in

© 2026 Lanfrica. Tous droits réservés. Tous les droits d'auteur des ressources affichées sur le site Web Lanfrica appartiennent aux détenteurs de droits d'auteur d'origine, sauf indication contraire explicite.

Ọjọ́-ọ̀la Èdè Yorùbá ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà

Domaine:

natural language processing

Type de record:

paper
Créateur:
AKI
Éditeur:
Uni
Hôte:
Apileko yii pitan ididele eko ede Yoruba ni orile-ede Amerika, o si so olokanojokan awon isoro to n koju awon oluko ati akekoo ede Yoruba ni orile-ede naa, ki o too wa wo sakun ojo-ola eto eko naa nile Amerika. Lara awon aba ti apileko yii gbe kale ki ojo-olo ede Yoruba le dara sii ni: kiko iwe ikoni to ba igba mu, to si see lo pelu imo ero, fifun awon akekoo ni imoran nipa iwulo kiko ede ajoji bi ede akonkunteni, fifi enu ko nipa fonti lati maa fi te Yoruba lori konputa ati odiwon fun ikoni lekoo, titi o fi kan ipese anfani fun awon akekoo lati lo si Naijiria nibi ti awon elede naa ti n lo o ni gbogbo igba.

Visit

doi.org

Languages

ArigidiYoruba

Licenses

https://creativecommons.org/licenses/by-nc/4.0

Similaires

Àgbéyẹ̀wò Ipa Èdè, Àṣà, àti Lítíréṣọ̀ Yorùbá Nínú ọ̀gbagadè Ìtàn Orílẹ̀-èdè NàìjíríàLílo Ìmọ̀ ẹ̀rọ láti kọ́ni ní Èdè YorùbáLílo ‘BBC News Yorùbá’ fún Ẹ̀kọ́ Yorùbá ní Amẹ́ríkàÀTÚNYẸ̀WÒ SÍLÉBÙ OLÓHÙN ÒKÈ (SOO) NÍ Ẹ̀KA ÈDÈ ARIGIDI

Àgbéyẹ̀wò Ipa Èdè, Àṣà, àti Lítíréṣọ̀ Yorùbá Nínú ọ̀gbagadè Ìtàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Ede, asa ati litireso je mayami eta-oko to n safihan idanimo awon eniyan kan. Ni orile-ede Naijiria,

Lílo Ìmọ̀ ẹ̀rọ láti kọ́ni ní Èdè Yorùbá

Apileko yii se alaye to kun lori bi a se le lo awon imo ero tuntun (technology) fun akoyege ede Yoru

Lílo ‘BBC News Yorùbá’ fún Ẹ̀kọ́ Yorùbá ní Amẹ́ríkà

I examined various means by which interviews made on ‘BBC News Yorùbá’ could be employed in Yorùbá l

ÀTÚNYẸ̀WÒ SÍLÉBÙ OLÓHÙN ÒKÈ (SOO) NÍ Ẹ̀KA ÈDÈ ARIGIDI

Àṣamọ̀ Sílébù Olóhùn Òkè (SOO) ni wúnrẹ̀n gírámà tó máa ń jẹyọ láàárín olùwà àti àpólà ìṣe nínú Yor