Logo Lanfrica
  • Home
  • Atlas
  • Insights
  • Docs
  • Sign in

© 2026 Lanfrica. All rights reserved. All copyrights of the resources shown on the Lanfrica website belong to the original copyright holders, unless explicitly stated otherwise.

Lílo Ìmọ̀ ẹ̀rọ láti kọ́ni ní Èdè Yorùbá

Domain:

natural language processing

Record type:

paper
Creator:
Olu
Publisher:
Uni
Host:
Apileko yii se alaye to kun lori bi a se le lo awon imo ero tuntun (technology) fun akoyege ede Yoruba, papaa julo nipa lilo awon ere idaraya keekeeke lori ero konputa fun kiko ede Yoruba. Ninu apileko naa, a safihan awon ere onimo ero gbajugbaja ti oluko le samulo won fun kiko ede Yoruba gege bii Jeopardy (Jeopaadi), Who Wants to be a Millionaire (Ta lo fe dololoa?), ati Wordsearch (Isawari Oro). Nipari, apileko naa se alaye to kun nipa arifani ati isoro ti o so mo awon ere ori ero wonyi.

Visit

doi.org

Languages

Yoruba

Licenses

https://creativecommons.org/licenses/by-nc/4.0

Similar

Ọjọ́-ọ̀la Èdè Yorùbá ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàLílo ‘BBC News Yorùbá’ fún Ẹ̀kọ́ Yorùbá ní Amẹ́ríkàÀTÚNYẸ̀WÒ SÍLÉBÙ OLÓHÙN ÒKÈ (SOO) NÍ Ẹ̀KA ÈDÈ ARIGIDIÀgbéyẹ̀wò Ipa Èdè, Àṣà, àti Lítíréṣọ̀ Yorùbá Nínú ọ̀gbagadè Ìtàn Orílẹ̀-èdè NàìjíríàÌMỌ̀ ÌJÌNLẸ̀ YORÙBÁ NÍPA OBÌ DÍDÀ GẸ́GẸ́ BÍ ÌLÀNÀ YẸ̀MÍWÒ

Ọjọ́-ọ̀la Èdè Yorùbá ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà

Apileko yii pitan ididele eko ede Yoruba ni orile-ede Amerika, o si so olokanojokan awon isoro to n

Lílo ‘BBC News Yorùbá’ fún Ẹ̀kọ́ Yorùbá ní Amẹ́ríkà

I examined various means by which interviews made on ‘BBC News Yorùbá’ could be employed in Yorùbá l

ÀTÚNYẸ̀WÒ SÍLÉBÙ OLÓHÙN ÒKÈ (SOO) NÍ Ẹ̀KA ÈDÈ ARIGIDI

Àṣamọ̀ Sílébù Olóhùn Òkè (SOO) ni wúnrẹ̀n gírámà tó máa ń jẹyọ láàárín olùwà àti àpólà ìṣe nínú Yor

Àgbéyẹ̀wò Ipa Èdè, Àṣà, àti Lítíréṣọ̀ Yorùbá Nínú ọ̀gbagadè Ìtàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Ede, asa ati litireso je mayami eta-oko to n safihan idanimo awon eniyan kan. Ni orile-ede Naijiria,

ÌMỌ̀ ÌJÌNLẸ̀ YORÙBÁ NÍPA OBÌ DÍDÀ GẸ́GẸ́ BÍ ÌLÀNÀ YẸ̀MÍWÒ

Àṣamọ̀ Igba ọ̀nà ló wọlé àwúrèbe ni ìlànà Yẹ̀míwò nílẹ̀ Yorùbá. Yẹ̀míwò lè jẹ́ nípa Ifá dídà (Ikin