Logo Lanfrica
  • Home
  • Atlas
  • Insights
  • Docs
  • Sign in

© 2026 Lanfrica. All rights reserved. All copyrights of the resources shown on the Lanfrica website belong to the original copyright holders, unless explicitly stated otherwise.

ÀTÚNYẸ̀WÒ SÍLÉBÙ OLÓHÙN ÒKÈ (SOO) NÍ Ẹ̀KA ÈDÈ ARIGIDI

Domain:

natural language processing

Record type:

paper
Creator:
OKEJIM
Publisher:
Láà
Host:avatar
Àṣamọ̀ Sílébù Olóhùn Òkè (SOO) ni wúnrẹ̀n gírámà tó máa ń jẹyọ láàárín olùwà àti àpólà ìṣe nínú Yorùbá Àjùmọ̀lò àti àwọn ẹ̀ka èdè rẹ̀, èyí tí Arigidi jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ẹ̀ka èdè náà. Ìmọ àtijọ́ lórí SOO ní ẹ̀ka èdè Arigidi ni pé ó jẹ́ atọ́ka afànámọ́mìí tàbí wúnrẹ̀n tí ó ń tọ́ka sí ìṣẹ̀lẹ̀ tó ti parí. Ṣùgbọ́n ẹ̀rí tuntun tí a yànnàná rẹ̀ nínú bébà yìí fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé wúnrẹ̀n náà ń ṣàfihàn àbúdà iye olùwá nínú gbólóhùn ní. Torí náà, ìrísí méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní SOO ní èdè Arigidi ní. Ìrísí àkọ́kọ́ ní ‘á’, èyí tí ó máa ń jẹyọ nígbà tí olùwà inú gbólóhùn bá jẹ́ ẹyọ. Ìrísí rẹ̀ kejì sì ni ‘wá’, tí ó máa ń jẹyọ nígbà tí olùwà bá jẹ́ ọ̀pọ̀. Kókó-ọ̀rọ̀: Sílébù olóhùn òkè, àbùdá iye, Ìrísí, Arigidi

Visit

doi.orgzenodo.org

Languages

ArigidiSooYoruba

Licenses

Creative Commons Attribution 4.0 Internationalhttps://creativecommons.org/licenses/by/4.0/legalcode

Similar

Ọjọ́-ọ̀la Èdè Yorùbá ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàLílo Ìmọ̀ ẹ̀rọ láti kọ́ni ní Èdè Yorùbá

Ọjọ́-ọ̀la Èdè Yorùbá ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà

Apileko yii pitan ididele eko ede Yoruba ni orile-ede Amerika, o si so olokanojokan awon isoro to n

Lílo Ìmọ̀ ẹ̀rọ láti kọ́ni ní Èdè Yorùbá

Apileko yii se alaye to kun lori bi a se le lo awon imo ero tuntun (technology) fun akoyege ede Yoru