Logo Lanfrica
  • Accueil
  • Atlas
  • Analyses
  • Documentation
  • Sign in

© 2026 Lanfrica. Tous droits réservés. Tous les droits d'auteur des ressources affichées sur le site Web Lanfrica appartiennent aux détenteurs de droits d'auteur d'origine, sauf indication contraire explicite.

Ewì Gẹ́gẹ́ Bí Ètè Ogun Jíjà Láwùjọ

Créateur:
Luq
Éditeur:
Uni
Hôte:
Oríṣìíríṣìí ète ni àwọn jagunjagun máa ń ṣàmúlò láyé àtijọ́ láti fi ṣẹgun ̀ ọ̀ tá. Díẹ̀ lára àwọn ète wọ̀ nyí ni ìdẹ́ rùbani, olè jíjà, agbára oògùn àti bíba irè oko àwọn ọ̀ tá wọn jẹ́ . Àwọn iṣẹ́ ìwádìí ti wáyé lóríṣìíríṣìí lórí ogun jíjà láwùjọ Yorùbá ṣùgbọ́ n kò sí iṣẹ́ ìwádìí kan gbòógì tó ṣe àgbéyẹ̀ wò ewì gẹgẹ́ ́ bí ète ogun jíjà ní pàtó, ní kíkún. Lọ́ nà àti dí àlàfo yìí, iṣẹ́ ìwádìí yìí fi ojú ìmọ̀ - ìtàn-mọ́ -lítíréṣọ̀ ṣe àtẹgùn láti ṣe àgbéyẹ ̀ ̀ wò ewì gẹgẹ́ ́ bí ète ìjagun ní àwùjọ Yorùbá. A mọ̀ -ọ́ nmọ̀ ṣàṣàyàn àwọn ogun tí ó ti wáyé nínú ìtàn láwùjọ Yorùbá nínú èyí tí wọ́ n ti ṣàmúlò ewì láti ṣẹgun ni. A fi ọ ́ ̀ rọ̀ wá àwọn àgbà àti àwọn tó nímọ̀ nípa ogun lẹ́ nu wò. Bákan náà ni a ṣe ìtúpalẹ̀ àwọn ewì tí wọ́ n lò, lọ́ nà àti mọ ìdí tí ète náà fi mú ọ̀ tá tí wọ́ n dẹ ẹ́ fún. Orin lóríṣìíríṣìí àti oríkì ni iṣẹ́ ìwádìí ṣe àfihàn pé wọ́ n lò gẹgẹ́ ́ bí ète láti mú ọ̀ tá nínú ogun tí a yẹ̀ wò. Bákan náà ni ó hàn gbangba nínú iṣẹ́ ìwádìí yìí pé ewì gẹgẹ́ ́ bí ète mú àwọn ọ̀ tá nítorí ọ̀ nà tí wọ́ n gbà lò ó fún ìdẹ́ rùbani, ìdájàsílẹ̀ , ìtannijẹ, ìránnilétí, ẹ̀bẹ̀ àti àyẹ́ sí. Ìgúnlẹ̀ iṣẹ́ ìwádìí ni pé idà olójú méjì ni ewì jẹ́ . Bí a ṣe le lò ó gẹgẹ́ ́ bí ète ìdógunsílẹ̀ náà ni a lè lò ó láti pẹ̀rọ̀ ogun. Nítorí náà, ewì tí í ṣe ogún ìbí Yorùbá ni a le ṣàmúlò láti dènà tàbí pẹ̀tù sí aáwọ̀ kí ó tó di ogun lọ́ nà àti mú àlàáfíà àti ìdàgbàsókè bá àwùjọ.

Visit

doi.org

Languages

Yoruba

Licenses

https://creativecommons.org/licenses/by-nc/4.0

Similaires

Àrokò Gẹ́gẹ́ bí Ọ̀ nà Ìbánisọ̀rọ̀ Láàárín Àwọn BabaláwoÌMỌ̀ ÌJÌNLẸ̀ YORÙBÁ NÍPA OBÌ DÍDÀ GẸ́GẸ́ BÍ ÌLÀNÀ YẸ̀MÍWÒ

Àrokò Gẹ́gẹ́ bí Ọ̀ nà Ìbánisọ̀rọ̀ Láàárín Àwọn Babaláwo

Àrokò jẹ́ ọ̀ nà ìbánisọ̀ rọ̀ nípa ṣíṣàmúlò àmì tàbí èdè awo. Ìran Yorùbá ò fẹ́ ràn láti máa fi gbogb

ÌMỌ̀ ÌJÌNLẸ̀ YORÙBÁ NÍPA OBÌ DÍDÀ GẸ́GẸ́ BÍ ÌLÀNÀ YẸ̀MÍWÒ

Àṣamọ̀ Igba ọ̀nà ló wọlé àwúrèbe ni ìlànà Yẹ̀míwò nílẹ̀ Yorùbá. Yẹ̀míwò lè jẹ́ nípa Ifá dídà (Ikin