Logo Lanfrica
  • Accueil
  • Atlas
  • Analyses
  • Documentation
  • Sign in

© 2026 Lanfrica. Tous droits réservés. Tous les droits d'auteur des ressources affichées sur le site Web Lanfrica appartiennent aux détenteurs de droits d'auteur d'origine, sauf indication contraire explicite.

Àrokò Gẹ́gẹ́ bí Ọ̀ nà Ìbánisọ̀rọ̀ Láàárín Àwọn Babaláwo

Domaine:

natural language processing

Type de record:

paper
Créateur:
Olú
Éditeur:
Uni
Hôte:
Àrokò jẹ́ ọ̀ nà ìbánisọ̀ rọ̀ nípa ṣíṣàmúlò àmì tàbí èdè awo. Ìran Yorùbá ò fẹ́ ràn láti máa fi gbogbo ẹnu sọ̀ rọ̀ , nítorí náà wọ́ n nífẹ̀ ẹ́ sí lílo èdè ìjìnlẹ̀ tàbí ohun tí ó ní ìtumọ̀ ìjìnlẹ̀ nínú àṣà wọn fún ìbánisọ̀ rọ̀ . Ọ̀pọ̀ lọpọ̀ onímọ̀ tí ṣiṣẹ́ lórí pàtàkì àrokò láàárín àwọn Yorùbá àmọ́ ọ̀ wọ́ já wọn ò tí dé ibi àrokò láààrín àwọn babaláwo. Pépà yìí ṣe àgbẹ́ yẹ̀ wò àrokò gẹ́ gẹ́ bíi ọ̀ nà ìbánisọ̀ rọ̀ láàárín àwọn babaláwo láwùjọ Yorùbá. Tíọ́ rì ìmọ̀ ìlò-àmi ni a gùnlé láti fi sọ ìtumọ̀ àwọn ohun èlò ìbánisọ̀ rọ̀ láàárín àwọn bábaláwo. Àwọn détà tí a lò ni a gbà lọ́ dọ̀ àwọn àṣàyàn babaláwo, èyí tí a sì ṣàtúpalẹ̀ wọn pẹ̀ lú tíọ́ rì àmúlò. Iṣẹ́ ìwádìí yìí sàlàyé díẹ̀ lára àwọn ohun ìpàrokò, yálà èyí tí o jẹ́ gbólóhùn tàbí èyí tí o jẹ́ ohun èlò àrídìmú tí àwọn babaláwo ń lò fún ìbánisọ̀ rọ̀ awo láàárín ara wọn pẹ̀ lú ọ̀ nà tí wọn ń gbà lò wọ́ n. Pépà yìí tan ìmọ́ lẹ̀ sí orísìírísìí ohun èlò ìpàrokò àti ọ̀ nà tí àwọn babaláwo ń gbà ṣàmúlò wọn fún ìbánisọ̀ rọ̀ láàárín ara wọn. Àpilẹ̀ kọ yìí fi hàn kedere pé ṣíṣe àmúlò àrokò láwùjọ le ṣe ìrànlọ́ wọ́ láti jẹ́ kí á ní àsírí àwọn ohun tí a kò fẹ́ jẹ́ kó hànde. Ó tún jẹ́ kí a mọ̀ pé, kò sí ẹgbẹ́ tàbí àwùjọ kan lábẹ́ àkóso bó ti wù kó rí tí kò ní ọ̀ nà ìbánisọ̀ rọ̀ alárokò láàárín ara wọn.

Visit

doi.org

Languages

Yoruba

Licenses

https://creativecommons.org/licenses/by-nc/4.0

Similaires

ÈDÈ BÍ ÒDÌ-ÀDÁ FÚN ÌBÁNISỌ̀RỌ̀ NÍNÚ ÀWỌN ÀṢÀYÀN ORIN HABEEB ỌMỌLÁLỌMÍEwì Gẹ́gẹ́ Bí Ètè Ogun Jíjà LáwùjọÌMỌ̀ ÌJÌNLẸ̀ YORÙBÁ NÍPA OBÌ DÍDÀ GẸ́GẸ́ BÍ ÌLÀNÀ YẸ̀MÍWÒÀgbéyẹ̀wò “Digital Nollywood” (Ọ̀ rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré) àti “Ògbóǹtarìgì”

ÈDÈ BÍ ÒDÌ-ÀDÁ FÚN ÌBÁNISỌ̀RỌ̀ NÍNÚ ÀWỌN ÀṢÀYÀN ORIN HABEEB ỌMỌLÁLỌMÍ

Àṣamọ̀

&l

Ewì Gẹ́gẹ́ Bí Ètè Ogun Jíjà Láwùjọ

Oríṣìíríṣìí ète ni àwọn jagunjagun máa ń ṣàmúlò láyé àtijọ́ láti fi ṣẹgun ̀ ọ̀ tá. Díẹ̀ lára àwọn èt

ÌMỌ̀ ÌJÌNLẸ̀ YORÙBÁ NÍPA OBÌ DÍDÀ GẸ́GẸ́ BÍ ÌLÀNÀ YẸ̀MÍWÒ

Àṣamọ̀ Igba ọ̀nà ló wọlé àwúrèbe ni ìlànà Yẹ̀míwò nílẹ̀ Yorùbá. Yẹ̀míwò lè jẹ́ nípa Ifá dídà (Ikin

Àgbéyẹ̀wò “Digital Nollywood” (Ọ̀ rọ̀ láti ẹnu àwọn àgbà òṣèré) àti “Ògbóǹtarìgì”

Digital Nollywood jẹ́ iṣé ìwádìí dígítà tí ó bẹ̀ rẹ̀ ní 2018 láti ṣe àgbékalè ìtàn fíìmù ní Nàìjíríà